Káàkiri àgbáyé ni wọn ti ń bá Alàgbà Kọ́láwọlé Oyewọ kẹ́dùn ikú ìyàwó rẹ̀, Yeye Benedicta Oyewọ to kú lópin ọ̀sẹ̀ to kọjá.
Obìnrin náà là gbọ pé ó jáde láyé lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà tó ti wà lórí idubulẹ àìsàn rọpa-rọsẹ.
Ọdún 2013 ni wọn yàn Olóògbé yìí gẹ́gẹ́ bí Yeye Balógun tí Ọba-Ilé.
Ọjọ́ kọkandinlọgbọn sì ọgbọ́n ọjọ́ oṣù yìí ni eto ìsìnkú yóò wáyé.
No comments:
Post a Comment