ÈTÒ ÌDÌBÒ ÌPÍNLẸ̀ ÒNDÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ PẸ́RẸU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, October 10, 2020

ÈTÒ ÌDÌBÒ ÌPÍNLẸ̀ ÒNDÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ PẸ́RẸU


Bí ẹ ṣe ń ka ìròyìn yìí eto idibo gómìnà tí bẹ̀rẹ̀ ni ìpínlẹ̀ Òndó, òní sì làwọn èèyàn yóò mọ ẹni táwọn aráàlú ń fẹ́. 

Arákùnrin Rotimi Akeredolu, Eyitayọ Jẹgẹdẹ àti Agboọla Ajayi làwọn mẹ́ta tí wọn gbajumọ dáadáa láàárín àwọn oludije.







No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI