OLUWO BÁ AKARIGBO ILẸ̀ RẸ́MỌ LÁLEJÒ, L'AKARIGBO BÁ SỌ̀RỌ̀ ÌWÚRÍ NÍPA OLUWO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, October 10, 2020

OLUWO BÁ AKARIGBO ILẸ̀ RẸ́MỌ LÁLEJÒ, L'AKARIGBO BÁ SỌ̀RỌ̀ ÌWÚRÍ NÍPA OLUWO


Olori awọn Ọba ilẹ Rẹmọ, Ọba Babatunde Adewale Ajayi, iyẹn Akarigbo t'ilẹ Rẹmọ lo tí gba Ọba AbdulRọsheed Adewale Akanbi, Oluwo t'ilu Iwo nípinlẹ Ọṣun lálejò ni Ààfin ẹ tó wà n'ilu Ṣagamu. 
 
 
Oni ti i ṣe Satide-Abamẹta ni Akarigbo tílẹ Rẹmọ n'ipinlẹ Ogun gba ọba Telu Kinni, Ọba Akanbia lálejò, to si ni ọba naa ti mu idagbasoke to lọọrin ba ilu Iwo.
 
Akarigbo ni nnkan t'oun ba nilẹ nigba toun ṣabẹwo silu Iwo tẹlẹ ti yatọ si nnkan to wa nibẹ lasiko yii, paapaa latigba ti Ọba Akanbi ti de ipo awọn baba nla rẹ.
 
 
 
 


 
 
 
 


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI