ÈYÍ NI DÍẸ̀ LÁRA ÀWỌN TÓ TI N JẸ ÀǸFÀÀNÍ OWÓ ÌṢÒWÒ NÍ KWARA, ORIN ỌPẸ NI WỌN Ń KỌ KIRI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, September 4, 2020

ÈYÍ NI DÍẸ̀ LÁRA ÀWỌN TÓ TI N JẸ ÀǸFÀÀNÍ OWÓ ÌṢÒWÒ NÍ KWARA, ORIN ỌPẸ NI WỌN Ń KỌ KIRI


Gbogbo àwọn tí ẹ ń wo yìí ni wón ti bẹ̀rẹ̀ si i jẹ́ mùdùnmúdùn eto òṣèlú awaarawa lábẹ́ ìṣàkóso Gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq tipinlẹ Kwara nípasẹ̀ Owó Ìṣòwò tí wọn tí rí gbà.

Àwọn tí kò dín ni ẹgbẹ̀rún kan ààbọ̀ lè díẹ̀ ni wọn ti bẹ̀rẹ̀ si i gba owó náà, tí wón sì ń dúpẹ́ lọ́wọ́ gómìnà wọn, AbdulRazaq.











No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI