Ẹ WOJU AWỌN ỌMỌ TI WỌN JI GBE KAAKIRI NAIJIRIA AT'AWỌN TO JI WỌN GBE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, September 16, 2020

Ẹ WOJU AWỌN ỌMỌ TI WỌN JI GBE KAAKIRI NAIJIRIA AT'AWỌN TO JI WỌN GBE


Awọn ọmọ ti ẹ n wo yii l'awọn oniṣẹ-ibi ji gbe kaakiri awọn ipinlẹ to wa lorilẹ-ede Naijiria, ti wọn si n fi wọn ṣoowo ẹru, ṣugbọn t'awọn ọlọpaa ti pada tu wọn silẹ ninu igbekun ti wọn wa.

Laarin awọn ọmọ naa ni wọn tun ti ṣawari ọmọ ọdun mẹẹdogun kan pẹlu oyun ninu ẹ, iyẹn n'ipinlẹ Anambra

Alukoro ọlọpaa ipin;ẹ naa, Haruna Mohammed lo gbe iroyin naa s'awọn akọroyin leti l'ọjọ Iṣẹgun, Tusidee ana wi pe awọn obinrin meji ati ọkunrin mẹta ni wọn wa n'idi iṣẹ naa, to si ni wọn yoo f'oju ba ile ẹjọ laipẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI