Ṣé ni ariwo ibanujẹ ńlá mi ín tún sọ lagboole àwọn òṣeré tíátà laaarọ òní ọjọ́ Aje, Mọnde nígbà tí Alagba Yekini Oyedele táwọn èèyàn tún mọ sì Baba Lẹgba jáde láyé.
Baba Lẹgba lọ jáde láyé lẹ́yìn àìsàn rampẹ ni kò pé tó rawọ ẹ̀bẹ̀ sáwọn ẹlẹyinju àánú káàkiri àgbáyé fún àánú àti iranlọwọ
Èyí ni ọ̀rọ̀ tó sọ gbẹyin kò too ku
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn náà ń bọ̀
No comments:
Post a Comment