AWỌN EEYAN ṢI N SỌRỌ LORI ILE AWOṢIFILA TI IYABỌ OJO ṢI L'EKOO (FỌTO) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, September 11, 2020

AWỌN EEYAN ṢI N SỌRỌ LORI ILE AWOṢIFILA TI IYABỌ OJO ṢI L'EKOO (FỌTO)


Titi di asiko ti a kọ iroyin yii tan ati asiko ti ẹ fi n ka iroyin yii l'awọn eeyan kaakiri agbaye ṣi n sọrọ lori ile awoṣifila ti gbajumọ oṣere tiata nni, Iyabọ Ojo Fespris ṣi laipẹ yii n'ilu Eko.

Ko s'ohun meji to mu k'awọn eeyan ṣi maa sọrọ lori ile naa, bi ko ṣe awọn nnkan to wa ninu ile naa, eyi ti wọn ni ki i ṣe owo kekere ni Iyabọ Ojo fi ra ile naa, to si mu ki wọn maa ki aje ku ikalẹ.

Lara awọn t'awọn eeyan n sọ ni pe ko daju pe idi iṣẹ tiata ati ile ounjẹ ti Iyabọ yan laayo lo ti ri owo to fi ra ile naa, t'awọn kan si n sọ pe Iyabọ ni awọn baba-n-gbẹjọ to da owo ile naa fun un.

Awọn aworan bi inu ile naa ṣe ri ree:













No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI