Minisita fun eto araalu, abojuto iṣẹlẹ ajalu ati igbe-aye afẹ {Humanitarian Affairs, Disaster Management and Social Development}, Hajiya Sadiya Umar Farouq ti sọ pe ọrọ toun ko sọ l'awọn iroyin gbe kaakiri wi pe gbogbo ọmọ Naijiria ni wọn gba nnkan iranwọ lasiko konilegbele.
Ọjọ Mọnde ana ni Farouq sọrọ yii jade nibi ipade olojoojumọ awọn igbimọ Aarẹ to n ri sọrọ Covid-19 (Presidential Task Force) nílu Abuja.
Farouq ni ko ṣee ṣe ki wọn fu gbogbo ọmọ orilẹ-ede Naijiria ni nnkan iranwọ lasiko konilegbe, nitori pe wọn pọju nnkan t'awọn eeyan ko lero lọ.
No comments:
Post a Comment