Ariwo 'ẹ gbà wá o' l'awọn ara agbègbè Akinyẹle n'ilu Ibadan, ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tún mú sẹnu lọ́jọ́ Abamẹta tó kọjá yìí, nígbà tí wón ní Sunday Shodipe tọwọ àwọn ọlọpaa tẹ, ṣùgbọ́n tó tún pòórá mọ wọn lọ́wọ́ pá obìnrin kan dànù.
Nnkan bí aago mẹ́ta ọ̀sán kọjá ìṣẹ́jú díẹ̀ niṣẹlẹ náà waye.
Funmilayọ tí wọn tún ń pè ní Iya Ibeji lórúkọ ẹni tó ṣá ladaa lórí pá. Ibi tí wón ti ń gbé Funmilayọ káàkiri ọsibitu fún itọju lo tí kì.
No comments:
Post a Comment