Epe rabandẹ-rabandẹ l'awọn abiyamọ kaakiri agbaye n gbe iyaale ile kan, Abigail Agbubla ṣẹ lori bo ṣe gbe majele f'awọn ọmọ rẹ jẹ.
Ori ikanni ayelujara ni fọto Abigail at'awọn ọmọ rẹ gba kan laipẹ yii.
Ohun ti a gbọ ni pe inu lo bi Abigail to fi ṣe bẹẹ, wọn ni owo ounjẹ ti ko ri gba lọwọ ọkọ rẹ lo bii ninu to fi ṣeku pa awọn ọmọ naa ti wọn ni ọjọ ori wọn ko ju ọdun meji si marun-un lọ.
No comments:
Post a Comment