FỌTO/FÍDÍÒ! ÈYÍ NI BI WỌN ṢE SÌNKÚ KAṢAMU N'IJẸBU IGBÓ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, August 9, 2020

FỌTO/FÍDÍÒ! ÈYÍ NI BI WỌN ṢE SÌNKÚ KAṢAMU N'IJẸBU IGBÓ


Lónìí ọjọ́ Àìkú, Sannde ni Sẹnetọ Buruji Kaṣamu wọ ká ilẹ̀ sún lẹ́yìn tó gbà ekuru jẹ lọ́wọ́ ẹbọra lọ́jọ́ Abamẹta, Satide àná.

Ẹsẹ̀ kò gbà èrò nílé Kaṣamu tó wà n'ilu Ijẹbu-Igbo, níbi tí wọn sìn ín sí nilana Mùsùlùmí. 

Báwọn kan ṣe ń gbé ara ṣanlẹ, tí wọn ń wá omijé mú, bẹ́ẹ̀ làwọn kan ń barajẹ gidigidi. 

Gómìnà Dapọ Abiọdun kò gbẹyin níbi eto ìsìnkú náà. 

Diẹ rèé lára àwọn fọto àti fídíò bí ìsìnkú náà ṣe lọ sí. 

Awon foto:







Fidio naa re e:


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI