Bí ẹ ṣe ń ka ìròyìn yìí, àwọn ọmọ ojú ogún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ìyẹn àwọn ṣọja ni wọn ti wá ní imurasilẹ láti kọjú ìjà sí àwọn afurasi ọ̀daràn wọn ní wón fẹẹ dá wàhálà ńlá nipinlẹ Kwara.
A gbọ pé ipinlẹ kan tó sunmọ Kwara làwọn afurasi ọ̀daràn náà tí wá sí ìjọba ìbílẹ̀ Baruten local ni ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀sẹ̀ yìí.
Bí olobo náà ṣe tá sì ìjọba ipinlẹ náà létí ni Gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq tí pàṣẹ pé káwọn ọmọ ojú ogún lọ kojú wọn.
No comments:
Post a Comment