EPL: MANCITY FẸẸ RA TỌRẸẸSI NI MILIỌNU MẸTALELOGUN EURO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, July 30, 2020

EPL: MANCITY FẸẸ RA TỌRẸẸSI NI MILIỌNU MẸTALELOGUN EURO


Ikọ ẹgbẹ́ agbabọọlu Manchester City tí sọ pé àwọn tí ṣetan láti ra Torres ni miliọnu mẹtalelogun euro (€23m). 

Pep Guardiola ni wọn lo o sọ ọmọ ogun ọdun naa di aayo ọkan rẹ lasiko yii, lẹyin ti Leroy Sane gba ẹgbẹ agbabọọlu Bayern Munich lọ.

Valencia la gbọ pe ohun naa ti ṣetan lati fi Torres silẹ, nigba ti wọn sọ pe ọdun kan pere lo ku ko lo pẹlu wọn.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI