Laaro oni ni ile igbimo asofin agba orile-ede Naijiria gba ijoba orile-ede yii lamoran lati yi oruko papako ofurufu t'ipinle Oyo loruko Gomina ana, Seneto Abiola Ajimobi to doloogbe laipe yii.
Okan lara awon Seneto orile-ede yii, Seneto Abdulfatahi Buhari lo daba naa, nigba ti Seneto Ibikunle Amosun keji re.
Nibi ijokoo naa l'awon Seneto yii ti dide iseju kan fun Gomina Ajimobi toun naa ti wa n'ipo naa tele, laaarin odun 2003 si odun 2007.
No comments:
Post a Comment