WÀHÁLÀ DÉ! ÀWỌN ARÁÀLÚ FI ẸSUN JÌBÌTÌ KAN BANKI ACCESS - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, June 28, 2020

WÀHÁLÀ DÉ! ÀWỌN ARÁÀLÚ FI ẸSUN JÌBÌTÌ KAN BANKI ACCESS


Pẹ̀lú ìbínú làwọn onibara tí wọn ń lo ọkàn lára àwọn banki tó gbajumọ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni ìyẹn ACCESS BANK fi ń ṣepe fáwọn alaṣẹ banki náà lórí bí wọn ṣe ń fi ojoojumọ lu wọn ní jìbìtì.

Owo kan tí wọn pé ní Stamp Duty la gbọ pé banki náà fi ń lu àwọn èèyàn ní jìbìtì, tí wọn sì ni obitibiti owó ni wọn ti yọ nínú àpò owó ilé ifowopamọ àwọn onibara wọn.

Díẹ̀ rèé lára ohun táwọn èèyàn ń sọ:










No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI