Laipẹ yìí ni gbajugbaja oṣere fuji nnì, Wasiu Alabi táwọn èèyàn mọ sì Pasuma gbé ọkàn lára àwọn ọmọ rẹ, Wariz Ayinde sórí ìkànnì ayélujára instagiraamu, níbi tó ti ń kii kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ẹ.
Nibe lo tún ti gbàdúrà fún un, táwọn èèyàn sì ń bàa yọ wí pé Ọlọ́run tún fi ọjọ́ kún ọjọ́ tí orí ọmọ náà láyé.
No comments:
Post a Comment