Ọga patapata fun ileeṣẹ aṣọbode lorilẹ-ede yii, Hameed Ali ti fẹ iyawo tuntun. Ilu Kano ni eto ayẹyẹ naa ti waye ni bonkẹlẹ.
Eyi waye lẹyin ọdun bii ọdun meji ti iyawo ẹ akọkọ, Hajiya
Hadiza Jummai Ali ku nilu Abuja. Ọjọ kọkandinlọgbọn, oṣu kẹsan ọdun 2018 l'obinrin naa jade laye l'ọsibitu kan n'ilu Abuja.
ọmọ mẹrin la gbọ pe o wa laaarin wọn ko too di pe obinrin naa fi aye silẹ.
Fọto bi ayẹyẹ naa ṣe lọ lẹ n wo n'isalẹ yii.
No comments:
Post a Comment