NÍTORÍ FỌTO TI GBAJUMỌ ÒṢERÉ TÍÁTÀ, INI EDO GBÉ SÍTA, OLÓLÙFẸ́ BY SẸKUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, May 28, 2020

NÍTORÍ FỌTO TI GBAJUMỌ ÒṢERÉ TÍÁTÀ, INI EDO GBÉ SÍTA, OLÓLÙFẸ́ BY SẸKUN


Ìyàlẹ́nu ńlá gbáà ni fọto tí ọkàn lára àwọn oṣerebinrin tó jẹ́ gbajugbaja, ìyẹn Ini Edo gbé síta ni nnkan bí wákàtí méjì seyin lórí ìkànnì ayélujára instagiraamu jẹ fáwọn olólùfẹ́.


Fọto tí ẹ ń wo yìí làwọn èèyàn ti bẹ̀rẹ̀ sii sọ oríṣiríṣi nípa rẹ, kòda tí ọkàn lára àwọn olólùfẹ́ obìnrin náà tún ń bẹbẹ pé kò fi òun ṣe adé orí. 


Ini Edo nínú fọto tó gbé sórí ayélujára náà lo tí ni báwọn èèyàn bá ń jáde lọ ṣíṣẹ, kí wọn má ṣe gbàgbé láti lo aṣọ ibomu-bonu wọn, kí wọn sì máa wà ní imọtoto. 

Wọ̀nyí lóhùn táwọn èèyàn sọ.





No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI