MỌTO GBÀ ỌLỌ́PÀÁ DANU L'EKOO, LÓJÚ ẸSẸ LO KU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, May 11, 2020

MỌTO GBÀ ỌLỌ́PÀÁ DANU L'EKOO, LÓJÚ ẸSẸ LO KU


Ajọ to ń rí sì ìṣẹ̀lẹ̀ pajawiri n'ipinlẹ Eko, LASEMA tí fìdí rẹ múlẹ̀ wí pé àwọn tí rí òkú ọlọ́pàá kan tí wọn pé ní Paul Omaji tí mọto pá dànù sì ẹgbẹ́ òpópónà n'ilu Eko. 

Agbegbe kan tí wọn ń pè ní Marwa, lójú ọ̀nà Lekki-Epe, ipinlẹ náà là gbọ pé ìṣẹ̀lẹ̀ yìí tí wáyé nirọlẹ ọjọ́ Sande, ìyẹn ana.

Ohun tá a gbọ ni pé lójú ẹsẹ ti mọto náà tí gba ọlọ́pàá yìí ló ti na pápá bora, tí kò sì sẹni to dá a mọ. 

Àwọn òṣìṣẹ́ LASEMA náà là gbọ pé wọn padà gbé òkú náà lọ sí mọṣuari ọsibitu ìjọba tí Marina. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI