LẸ́YÌN IKÚ IMAAMU AGBA ILẸ̀ Ẹ̀GBÁ, SHEIK ONIKIJIPA NÁÀ TÚN JÁDE LAYE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, May 26, 2020

LẸ́YÌN IKÚ IMAAMU AGBA ILẸ̀ Ẹ̀GBÁ, SHEIK ONIKIJIPA NÁÀ TÚN JÁDE LAYE


Ṣé ni gbogbo agboolé Mùsùlùmí jákèjádò tún bù sẹkun nígbà tí wọn gbọ nípa ikú àgba Mùsùlùmí nnì, Sheik Abubakri Sidiq Umar Onikijipa. 

Aarọ onii náà niroyin ikú Sheik Onikijipa náà dagbere fàyè kí kò pẹ tí Imaamu àgbà ilẹ̀ Ẹ̀gbá, Oloye Sheik Ayinde Liadi Ọrunṣolu jáde láyé. 

Sheik Onikijipa tí pupọ àwọn èèyàn tún mọ sì Aburidoh lo jẹ gbajumọ ẹlẹyinju àánú mẹkunnu, to sì ń ṣàánú fáwọn aláìní nígbà ayé ẹ. 

Olóògbé yìí jẹ ẹ̀gbọ́n sì Sheik Farouq Onikijipa tó jẹ́ gbajugbaja òní waasi àgbáyé. 

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn nípa ikú àgbà Mùsùlùmí nnà ń bọ laipẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI