Ni kété tí ìròyìn náà tí jáde síta wí pé ìjọba ipinlẹ Kwara pẹ̀lú ajọṣepọ ileeṣẹ Google fẹẹ dá àwọn èèyàn, pàápàá àwọn ọdọ l'ẹkọọ lórí bí wọn yóò ṣe bá àwọn akẹgbẹ wọn káàkiri àgbáyé fẹgbẹkẹgbẹ lọ́nà ìgbàlódé làwọn èèyàn ti bẹ̀rẹ̀ si í f'orukọ silẹ.
A mú ìròyìn náà wá fún un yín laipẹ yìí.
Lára àwọn ẹ̀kọ́ tí wọn fẹ ẹ kọ́ àwọn èèyàn ní: Fundamentals of Digital Marketing (Accredited certification by Grow with Google); Applied Digital tools and G Suites (certified by Grow with Google); Social Media Marketing; Graphic Design; Business Branding ati Presentation to Impress.
Díẹ̀ re e lára àwọn tó ti f'orukọ silẹ fún idanilẹkọọ náà tó bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ Tọside ijẹta.
No comments:
Post a Comment