YÉWÁNDÉ ÒNÍ TÍÁTÀ BÍMỌ TUNTUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, April 17, 2020

YÉWÁNDÉ ÒNÍ TÍÁTÀ BÍMỌ TUNTUN


Bí ẹ ṣe ń ka ìròyìn yìí, inú ìdùnnú àti ayọ̀ ni gbajugbaja oṣerebinrin nnì, Yéwándé Adekọya àti ìdílé rẹ wà báyìí lórí ọmọ obìnrin tuntun jòjòló tó ṣẹ̀ṣẹ̀ bí í.

Òní ni Yéwándé táwọn èèyàn tún ń pè ní Ọmọ Ẹlẹmọṣọ gbé ọmọ rẹ tuntun àti ọkọ tó bímọ fún sórí ìkànnì ayélujára káàkiri wí pé káwọn èèyàn bá òun dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nítorí pé òun náà tí di abiyamọ báyìí.




No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI