Àwọn mọto àti ọkada tí ẹ ń wo yìí ni Gomina Dapọ Abiọdun t'ipinlẹ Ogun ṣẹ̀ṣẹ̀ pín fún gbogbo ileeṣẹ eleto ààbò pátápátá n'ipinlẹ náà.
Ọjọ́ Iṣẹgun, Tuside ni Gomina Abiọdun yọnda àwọn ọkọ̀ náà fún wọn.
Lára àwọn tó gbà mọto náà ni ọlọ́pàá tí wọn gba mọto mọkandinlaadọrin {69}, QRS to gba mẹ́wàá, TRACE tó gbà mẹ́wàá, Sífù difẹnsi tòun náà gbà mẹ́rin.
Yàtọ̀ sí eyii, ileeṣẹ ológun gba mọto márùn-ún, DSS tó gbà méjì àti NIS tòun gba eyọkan.
Bẹẹ ni wọn tún gbà àwọn ọkada amuṣẹya
No comments:
Post a Comment