Bẹẹdi tí kò din ni ọgọ́ta lo gba ọsibitu ayasọtọ fún ibùdó ayẹwo àrùn aṣekupani tí COVID-19, èyí tí ìjọba ìbílẹ̀ Kwara ṣe lẹ ń wo yìí.
Ọ̀pọ̀ àwọn tó ń rí í ní wọn ń ṣe sadankata fún Gomina AbdulRahman AbdulRazaq lórí bo ṣé gbé ọsibitu náà kalẹ tó sì bá ọ́nà ìgbàlódé mú.
Ọsibitu náà, ìyẹn Sobi Specialist Hospital lẹ ń wo yìí, nibẹ náà ni wọn ti ń tọju àwọn tó ní àrùn COVID-19.
No comments:
Post a Comment