Ọrọ burúkú tòun tẹrin pẹlu báwọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà káàkiri ṣe sọ aarun aṣekupani tó ń tàn káàkiri àgbáyé lásìkò yìí, ìyẹn Coronavirus di ohun tí wọn fi ń ṣe awada láàárín ara wọn.
Kìí ṣe ahesọ wí pé aarun náà tí wọ Nàìjíríà, tó sì jẹ pe o ti ko ẹ̀rù sáwọn èèyàn lọ́kàn gidigidi.
Àwọn fọto imura arambara kan lo tí jáde sórí ayélujára báyìí níbi táwọn ọmọ orilẹ-èdè yìí tí ń arrun Coronavirus ṣe awada.
No comments:
Post a Comment