MI Ò KABAMỌ PÉ MO Ń BA BABA MI LAṢEPỌ - BALA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, March 16, 2020

MI Ò KABAMỌ PÉ MO Ń BA BABA MI LAṢEPỌ - BALA


Ọmọbìnrin kan tó pé ara rẹ ní Lala Bala lórí ìkànnì ayélujára tí Fesibuku {Facebook} tí sọ pé òun kò fìgbà kan rí kabamọ wí pé òun ń bá bàbá tó bí òun lọmọ laṣepọ.

Lala to ni ọmọdun mẹ́sàn-án lòun wá ti bàbà òun ti ń kona abẹ foun sọ pé ó ti mọ̀ òun lára pupọ.

Ọdọmọbinrin tọjọ orí ẹ kò ti í ju ọdún mọ ká lélógún {21years} lọ sọ pé gbogbo nnkan tòun ń fẹ́ ni bàbá òun ń ṣe foun, tóun kò sì ti í rí ìdí kan ni pàtó tòun yóò fi ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ọkùnrin mìíràn. 

Pupọ àwọn tó ká nnkan ti Lala Bala kọ yìí ló ń ṣe ní kayeefi nítorí pé wọn kò gbọ irú ẹ rí, táwọn kan sì ń bù ẹnu atẹ lu ọ̀rọ̀ tó sọ yìí.



No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI