Bo tilẹ jẹ pe inu Aarẹ orilẹ-ede Naijiria, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ ko fi bẹẹ dun pupọ lori ọna ti ayẹyẹ ọjọ ibi ọdun mẹtalelọgọrin rẹ to waye l'ọsẹ yii, sibẹ, orin ọpẹ lo gba ẹnu rẹ kan wi pe oun tun ri ọdun mi-in, tawọn eeyan kaakiri agbaye si n ba a yọ pupọ.
Aarun kan to n ja rain-rain kaakiri agbaye lasiko yii, iyẹn Coronavirus lo fa a ti Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ ṣe fa ọwọ eto naa sẹyin, nitori pe awọn eeyan jankan-jankan kaakiri agbaye lo yẹ ko wa nibẹ, ṣugbọn itankalẹ aarun naa ko faaye silẹ lati pe ero.
Diẹ re e lara bi eto ayẹyẹ naa ṣe lọ si i n'ilu Abẹokuta:
No comments:
Post a Comment