Ariwo ikúnlẹ abiyamọ lo gba ẹnu ọpọ àwọn èèyàn tó wà lágbègbè Salvation Transport Stop, Ọpẹbi n'ilu Eko lànàa ọjọ́ Abamẹta, ìyẹn Satide n'igba tí wọn dee de rí òkú baálé ilé kan, Tọpẹ Akinde lórí igi níbi tó ti ń mi jolonjolo.
Òṣìṣẹ́ àjọ to ń rí sì ìgbòkègbodò ọkọ n'ipinlẹ Eko, ìyẹn LASTMA ni wọn pé Tọpẹ, tí wọn sì loo tí ń ṣàìsàn láti bí ọjọ mélòó kan sẹ́yìn.
A gbọ pé aarun ọpọlọ kọlu Tọpẹ, tí wọn sì làwọn ẹbi ẹ lo ń gbé káàkiri láti lè rí ìwòsàn.
Ṣàdédé là gbọ pé àwọn ará agbegbe ti Tọpẹ pá ara rẹ sí yìí ni wón rí òkú rẹ, kò Tóò di pé wọn pariwo síta. Àwọn òṣìṣẹ́ eleto ààbò Ìpínlẹ̀ Eko, ìyẹn Neighborhood Safety Corps ni wọn padà gbé òkú rẹ lọ sí mọṣuari gẹ́gẹ́ bá a ṣe gbọ
No comments:
Post a Comment