O MA ṢE O! AṢITA IBỌN BA ỌMỌ IKOKO NI PORT HARCOURT - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, February 8, 2020

O MA ṢE O! AṢITA IBỌN BA ỌMỌ IKOKO NI PORT HARCOURT

Bi ki i ba a ṣe ọpẹlọpẹ Ọlọrun to ko ọmọdekunrin kekere jojolo kan ti a ko ti i mọ orukọ rẹ titi d'asiko ta a kọ iroyin yii tan ni, bo ya ki ba ti jẹ ipe Ọlọrun.

Ọta Ibọn naa
Ọmọdekunrin jojolo naa ti ọjọ ori ẹ ko ti i ju oṣu mẹsan an lọ naa la gbọ pe aṣita ibọn ba n'ikun l'adugbo kan ti wọn pe ni Mkpogu, Trans Amadi, Portharcourt ni alẹ ijẹta  tii ṣe Tọsidee.
 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI