L'ọsan onii làwọn aráàlú Ìwó ń'ipínlẹ̀ Ọṣun ṣe iwọde láti fi hàn wí pé àwọn wá lẹ́yìn Ọba AbdulRọṣheed Akanbi, Oluwo tilu Ìwó bíi ike, àti pé kò ṣeni tó lè rọ ọ l'oye.
Ọ̀rọ̀ tí wọn ń sọ ní pe ki lo fà á tí Ọba Ọgbaagba fẹẹ fi ọ̀pá ọwọ rẹ lu Oluwo pá.
Díẹ̀ re e lára àwọn fọto iwọde náà:
No comments:
Post a Comment