Gbogbo agboole pedepede ati sọrọsọrọ kaakiri orilẹ-ede Naijiria ati agbaye ni wọn n ṣ'ayẹyẹ ọjọ ibi Ọgbẹni Kọlawọle Atanda Adejojo t'ọpọ mọ si Kasnaty Sugar loni-in ti i ṣe ọjọ kọkanla, oṣu keji.
Bi wọn ba n sọ nipa awọn sọrọsọrọ ori redio ati tẹlifiṣan ti aye n gba tiẹ daadaa loni-in, ọkan pataki ni Kasnaty Elele jẹ, ti ki i si i ṣaimọ f'oloko, paapaa f'awọn ololufẹ amuludun.
Lati ọsẹ bi i meloo kan sẹyin la gbọ pe awọn ololufẹ ọkunrin naa ti n fi atẹjiṣẹ ikini ranṣẹ si Kasnaty fun ipalẹmọ, ṣugbọn ni kete ti aago mejila oru oni yii lu, la gbọ pe atẹjiṣẹ ti n pe ara wọn ran n'iṣẹ loriṣiriṣi.
Ọkunrin to saba maa n ja ẹja tutu ni gbogbo igba to ba ti n pari eto rẹ lori redio ati tẹlifiṣan naa ni wọn loo ti di ọkan lara awọn ọga agba n'ile-iṣẹ redio Splash to wa n'ilu Abẹokuta bayii.
Bi ẹ ba fẹẹ ki Kasnaty fun ayẹyẹ ọjọ ibi ẹ, nọmba ẹ ni ki ẹ fi atẹjiṣẹ ranṣẹ si i, 08032312479
-2:11
Happy Birthday to one of the GREATEST OAP in Ogun State, Kolawole Atanda Adejojo
- Happy birthday Kas, llnp...
Happy birthday wish you many more years ahead- See 9 more posts
NO TIME TO CHECK TIME, LET'S REJOICE WITH THE CELEBRANTS, KOLAWOLE ADEJOJO(KASNATY) & SESAN AKINPELU(CHELSEA BOBO). @kasnatysugar , @chelseaboboakinpelu
Happy birthday to you my good brother, Mr sugar.......Bombom...yiooooodabi alaaaaaaaa,to nba fosomi.......enjoy your day my brother❤❤❤❤
KOLAWOLE ATANDA ADEJOJO(KASNATY), IT'S YOUR DAY, MAY YOU CONTINUE TO REJOICE & CELEBRATE MORE YEARS ON EARTH. HAPPY BIRTHDAY KASNATY. @kasnatysugar
No comments:
Post a Comment