ÌYÀWÓ KOREDE WEALTH, GBAJUMỌ ÒṢERÉ TÍÁTÀ BÍMỌ ṢÍ CANADA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, February 20, 2020

ÌYÀWÓ KOREDE WEALTH, GBAJUMỌ ÒṢERÉ TÍÁTÀ BÍMỌ ṢÍ CANADA


'Ayọ̀ abara bintin, Ẹ kú ọwọ l'omi' ni esi ayọ̀ tí gbajugbaja oṣere tíátà nnì, Korede Wealth Obasan tí ń rí gbà látìgbà t'iroyin tí jáde síta wí pé ìyàwó rẹ bímọ obìnrin lanti-lanti.


Orí ojú òpó Instagram ni oṣere náà gbé àwòrán ìyàwó rẹ àti ọmọ tuntun náà sì, níbi tó ti ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run fún oriire ńlá yìí.




No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI