Afaimọ ni kí ọdọmọkunrin ẹni ọdún mọkandinlogun kan, Ekanem má padà fi ẹ̀wọ̀n jura lórí bi wọn lo ṣe ń dunkooko mọ màmá tó bí í l'ọmọ, tó sì fẹ́ ẹ pá a dànù.
Kayeefi l'ọrọ Ekanem ṣí ń jẹ fún ọpọ àwọn tó gbọ́ sì bo ṣe fún màmá tó bí í l'ọmọ l'oyun, l'ẹyin to dan oogun ìfẹ́ wo lára rẹ láti mọ bóyá ojúlówó ni. Ìlú Port Harcourt n'Ìpínlẹ̀ Rivers ni ìṣẹ̀lẹ̀ náà tí wáyé laipẹ yìí.
AWIKONKO gbọ́ pé Ekanem ṣẹ̀ṣẹ̀ jáde ilé ẹ̀kọ́ gírámà ni, tí wọn sì loo fẹran kò máa b'awọn obìnrin ṣeré, ṣùgbọ́n kò ní ọkàn akin láti dá ẹnu ìfẹ́ kọ obìnrin.
Gbogbo akitiyan Ekanem láti dá ẹnu ìfẹ́ kọ obìnrin, depodepo wí pé yóò bá wọn l'aṣepọ là gbọ́ pé ó já sí pàbó, eyii lọ fà á tí wọn loo fi gba ilé babaláwo lọ láti ṣe oogun tí yóò jẹ k'awọn obìnrin f'ẹran rẹ, tí yóò sì tún máa bá wọn l'aṣepọ bo ṣé wù ú.
Iyèméjì tí wọn ní Ekanem ṣe l'ọdọ babaláwo nípa oogun ìfẹ́ náà là gbọ pé ó mú kí bàbà náà lo ẹ̀dà ọ̀rọ̀ fún un wí pé bó bá dán án wo l'ara màmá tó bí í l'ọmọ, yóò l'oyun.
Wọn ní bí Ekanem ṣe de'le lọ́jọ́ náà lo tí sáré lo oogun yìí láti dán án wo lára màmá rẹ, tó sì jẹ pe lójú ẹsẹ lo tí bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́. Kò pé tí wọn ní Ekanem fi kí màmá rẹ mọ́lẹ̀, tó sì bẹ̀rẹ̀ sí í kò ibasun gbígbóná fún un.
Kàkà ki Ekanem dawọ iṣẹ́ dúró lára màmá rẹ, kò sì wá àwọn ọlọmọge ẹgbẹ́ rẹ láti máa lo oogun yìí fún lọ, ṣe ló kúkú sọ màmá náà di ẹ̀rọ ibalopọ (sex machine), to sì jẹ pe ojoojumọ ni wọn lo ń kó ibasun fún màmá rẹ.
Wọn ní kó pẹ tí màmá náà fi l'oyun. Oyún yìí ni wọn ní màmá náà ń béèrè bí wọn yóò ṣe ṣe é lọ́wọ́ ọmọ rẹ, tí wọn sì látìgbà náà lo tí ń dunkooko pé òun yóò pá màmá òun bí kò bá yọ oyún náà dànù.
Àwọn tí wọn gbọ́ sì iṣẹlẹ náà ni wọn gba màmá yìí nimọran wí pé kò lọọ fọrọ náà tó àwọn ọlọpaa létí, tí wọn sì lọọ gbé e.
Lójú ẹsẹ ni wọn lo tí ń bẹbẹ wí pé kí wọn ṣe òun jẹjẹ, àti pé òun kò ní í ṣe bẹ́ẹ̀ mọ.
Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa Ìpínlẹ̀ Rivers, Celestina Kalu to f'idi ìṣẹ̀lẹ̀ náà múlẹ̀ jẹ kò ye wá pé àwọn ṣí wá lórí ọ̀rọ̀ náà títí di àsìkò tá a fi kọ ìròyìn yìí tán.
No comments:
Post a Comment