ORIKI AMỌTẸKUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, January 24, 2020

ORIKI AMỌTẸKUN

"Àmọ̀tẹ̀kùn!

Ẹranko ìjayà, tí í ṣ'ẹ̀rù b'ẹtu.

Afínjú ọdẹ tíí dààmú ọ̀dàn.

Ẹ̀rù jẹ̀jẹ̀, onílà àlùmútù,

Ajẹran jeegun.

Olúọ́dẹ aginjù jámọláyà bí arira

Ò f'àìbúramúramù

Gb'ọ́mọ ẹran há'nu

Ẹranko a gbọ́n nínú gbọ́n l'óde,

Tíí fi Pẹ̀lẹ́-pùtù jayé inú ọ̀dàn".

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI