BỌSUN ỌLANIYI, ABẸOKUTA - Ṣẹnkẹn bayii ni idile Kọmureedi Olusọji Amosu to jẹ alaga ẹgbẹ akọroyin n'ipinlẹ Ogun n dun n'igba ti ẹgbẹ awọn oniṣegun lorilẹ-ede Naijiria, iyẹn Medical and Dental Council of Nigeria fi oye Oniṣegun da ọmọ rẹ, Pius Ọpẹyẹmi Amosu l'ọla.
Eto ayẹyẹ naa la gbọ pe o waye n'ile-ẹkọ fasiti t'iluu Ilọrin, yẹn University of Ilorin l'Ọjọbọ Tọside ana.
No comments:
Post a Comment