Agba Oloṣelu ipinlẹ Eko nni, to tun jẹ Aṣiwaju ninu ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP, Oloye Bọde George ti kede pe, oun naa yoo dije du ipo Aarẹ orilẹ-ede Naijiria l'odun 2023.
Agbenusọ Oloye Bọde George, Ọgbẹni Uthman Ṣodipẹ-Dosunmu lo ṣe ikede
naa niluu Abuja l'orukọ Bọde George.
O di ọmọ Yoruba keji to ti kede erongba wọn bayii,
iyẹn Bọde George ati Pasitọ Tunde Bakare.
No comments:
Post a Comment