GOMINA FAYẸMI RA AWỌN IRINṢẸ TO WULO FUN OPOPONA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, January 31, 2020

GOMINA FAYẸMI RA AWỌN IRINṢẸ TO WULO FUN OPOPONA

Gomina ipinle Ekiti, Omowe Kayọde Fayẹmi ti ṣ'agbekalẹ awọn irinṣẹ tuntun to wulo lati fi ṣe opopona to ja geere kaakiri ipinlẹ naa.
Awọn irinṣẹ naa ti wọn pe ni Asphalt Plant la gbọ pe lati oke-okun ni wọn ti ko wọn wa, ko le mu ki awọn iṣẹ akanṣẹ opopona to n lọ lọwọ tete pari.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI