Ẹsẹ ko gbero nibi ti wọn ti ṣayẹyẹ ikẹhin fun gbajugbaja Ojiṣẹ Ọlọrun nni, Reinhard Bonnke, ẹni tọpọ mọ-ọn si “The
Billy Graham of Africa”, ẹni to ku l'ọjọ keje oṣu kejila ọdun to kọja lẹni ọdun mọkandinlọgọrin (70).
Ko din ni ẹgbẹrun meji awọn eeyan ni wọn pade nibi eto naa to waye lorilẹ-ede United State, iyẹn ni ṣọọṣi Faith Assembly of God fun odindi wakati mẹta.
Lara awọn gbajugbaja Ojiṣẹ Ọlọrun bii T. D. Jakes, Benny Hinn,
ati Paula White ni wọn sọrọ nibẹ, ti wọn si sọ nipa iru apẹẹrẹ rere ti Oloogbe Bonnke jẹko too ku, atawọn ipa to fi silẹ ti ko le parẹ titi lai lagboole igbagbọ.
Diẹ re elara awọn fọto eto naa
No comments:
Post a Comment