Lati ọsẹ yo kọja yi ni Aafin Ọyọ ti n gbalejo awọn ọtọkuluu atawọn eeyan jankanjankan lawujọ orilẹ-ede yii, fun ti ipalẹmọ ayẹyẹ nla nni to n bọ lọna.
Lara awọn to tun ṣabẹwo si Alaafin Ọyọ, Iku Baba Yeye, Ọba Lamidi Ọlayiwọla Adeyẹmi l'awọn oṣere tiata Yoruba bi i Faithia Balogun Williams, Ọlaniyi Afọnja, Sanyẹri ati Adekọla Tijani, Kamilu Kọmpo.
No comments:
Post a Comment