Folukẹ Aduragbemi, Ọṣun - Gbogbo eto la gbọ pe o ti fẹẹ pari bayii fun ẹgbẹ Pedepede Yoruba, iyẹn Yoruba Broadcaster Association
of Nigeria, ẹka t'ipinlẹ Ọṣun lati da Akinrọgun Victor Mọbọlaji
Adewale l'ọla gẹgẹ bi 'Agbaṣaga Agbaye', iyẹn ẹni to n gbe Aṣa ati Iṣẹṣe Yoruba ga kaakiri agbaye.
Gẹgẹ bi lẹta ti ẹgbẹ naa kọ, eyi ti ẹda rẹ tẹ AWIKONKO l'ọwọ laipẹ yii ṣe fi ye wa, ọjọ karun un, oṣu kẹta ọdun yii ni eto idalọla naa fẹẹ waye n'ipinlẹ Ọṣun.
No comments:
Post a Comment