Ẹka ikẹkọọ ofin (Law Dept) ni
fasiti ipinlẹ Rivers to wa niluu Port Harcourt la gbọ pe Matilda, ẹni ọdun
mẹrinlelogun naa wa.
Ko si nnkan to jẹ ki iku
Matilda maa ya awọn eeyan lẹnu bi ko ṣe bi wọn ṣe sọ pe ṣe lawọn to gun un pa
kọkọ fipa ba a sun karakara, ko too di pe wọn gbẹmi ẹ.
Ko si nnkan to jẹ ki iku
Matilda maa ya awọn eeyan lẹnu bi ko ṣe bi wọn ṣe sọ pe ṣe lawọn to gun un pa
kọkọ fipa ba a sun karakara, ko too di pe wọn gbẹmi ẹ sinu ile to n gbe, eyi to
wa nitosi Eagle Island
Awọn ti wọn jọ n gbe la gbọ pe
wọn ri oku Matilda ninu agbara ẹjẹ, ki wọn too ranṣẹ sawọn ọlọpaa ti wọn pada
gbe oku ẹ lọ si mọṣuari.
Bẹẹ la gbọ pe ileeṣẹ ọlọpaa ti
bẹrẹ igbesẹ lati mọ awọn to ṣeku pa Matilda.
No comments:
Post a Comment