Ọpọ awọn ti wọn ri fọto gbajumọ oṣerebinrin tiata oloyinbo nni, Mercy Johnson Okojie atawọn mọlẹbi rẹ ni wọn n kan saara sii wipe o lo ara rẹ daadaa lẹyin ọmọ mẹta.
Ninu fọto naa la ti ri Mercy Johnson Okojie funra rẹ; Ọkọ rẹ, Ọmọba Odi Okojie atawọn ọmọ wọn, Purity, Henry ati Angel Okojie.
No comments:
Post a Comment