GBAJUMỌ AJIHINRERE, REINHARD BONNKE TI KU O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, December 7, 2019

GBAJUMỌ AJIHINRERE, REINHARD BONNKE TI KU O

Bi ẹ ṣe n ka iroyin yi, inu ibanujẹ ọkan lawọn mọlẹbi, paapaa awọn ọmọlẹyin atawọn ololufẹ gbajugbaja Ajihinrere agbaye nni, Reinhard Bonnke wa bayii lori bo ti ṣe fi aye silẹ lẹni ọdun mọkandinlọgọrin (79).

Iyawo Reinhard Bonnke, Arabinrin Anni Bonnke lo kede iku ọkọ rẹ lori ikanni ayelujara ti Facebook rẹ laipẹ yii, nibi to fi n to gbogbo awọn to ti gburo iṣẹ ọkọ rẹ kaakiri agbaye.

Ọdun 1967 la gbọ pe Oloogbe Bonnke bẹrẹ bẹrẹ iṣẹ ihinrere kaakiri agbaye, eyi to tun gbe wọ ilẹ Afrika.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI