SAIDI BALÓGUN PÀDÁNÙ MÀMÁ RE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, November 25, 2019

SAIDI BALÓGUN PÀDÁNÙ MÀMÁ RE


Ọ̀pọ̀ àwọn tó gbọ́ nípa ikú Màmá àgbà òṣèrékùnrin nnì, Saidi Balógun ni wọn ṣí ń kí kú aráfẹ́rakù títí dàsìkò tá a ṣàkójọpọ̀ ìròyìn yí tán.

Bo tilẹ̀ jẹ́ pé gbajúgbajà òṣèré tíátà náà kò sọ ọjọ́ tí Màmá rẹ, Jọláadé jáde láyé, síbẹ̀ orí ìkànnì ayélujára tí Instagram lo gbé fọ́tò Màmá rẹ yí sì, níbi tó ti ń fi tó gbogbo àwọn olólùfẹ́ rẹ létí.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI