ỌWỌ ỌLỌPAA TẸ ỌDỌMỌKUNRIN TO FẸẸ BẸ SODO L'EKOO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, November 25, 2019

ỌWỌ ỌLỌPAA TẸ ỌDỌMỌKUNRIN TO FẸẸ BẸ SODO L'EKOO

Kani kii ṣe pe awọn ọlọpaa tete de ibi iṣẹlẹ naa ni, o ṣee ṣe ki ọdọmọkunrin ti ẹ n wo yi ti dero ọrun pẹluu bi wọn ṣe lo fẹẹ bẹ sinu odo afara kẹta, iyẹn Third Main Land to wa l'Ekoo.

A gbọ pe bi ọdọmọkunrin naa ti a ko tii morukọ rẹ dasiko tá a ṣakojọpọ ìròyìn yí tán ṣe n ṣe lo fu awọn ọlọpaa lara ti wọn fi sare lọọ ba a.

 
loju ẹsẹ ni wọn ti muu lọ si teṣan Adekunle, nibi ti wọn ti ranṣẹ sawọn mọlẹbi rẹ lati waa muu.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI