Alaga ijọba ibilẹ Ifẹdọrẹ nipinlẹ Ondo, Ọnọrebu Alẹx Akinyẹmi ti gba aami ẹyẹ gẹgẹ bi ọkan laraawọn alaga ijọba ibilẹ ti wọn n ṣiṣẹ takun-takun kaakiri awọn agbegbe wọn.
Ọnọrebu Akinyẹmi to tun jẹ alaga gbogbo awọn alaga ijọba ibilẹ lorilẹ-ede Naijiria la gbọ pe wọn tun da lọla fun ti imọ ati ọgbọn to ni gẹgẹ bi adari rere.
No comments:
Post a Comment