Gomina ile ifowopamọ apapọ orilẹ-ede Naijiria (CBN), Ọmọwe Godwin Emefiele ti ba gbogbo awọn Gomina atawọn aṣoju gomina kaakiri ipinlẹ ti wọn ti n gbin Ẹgẹ, iyẹn Paaki lorilẹ-ede yi ṣepade papọ, wọn si ti tọwọ bọwe adehun lori ọna ti wọn yoo gba lati jẹ ki Paaki di ohun ti wọn tun fi n pa owo wọle.
Nibẹ ni wọn ti sọ awón ọna abayọ min in lori bi wọn yoo ṣe maa gbin Paaki lọpọ yanturu.
Ile ifowopamọ apapọ orilẹ-ede Naijiria to fikalẹ siluu Abuja nipade naa ti waye l'Ọjọbọ Tọside ana.
No comments:
Post a Comment