L'Ọjọbọ Tọside ọsẹ to kọja yi ni Aarẹ Muhammadu Buhari ati igbakeji rẹ, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo ṣepade pẹluu awọn agbaagba lẹka eto ọrọ aje, eyi to maa n waye loṣooṣu niluu Abuja.
Ko pẹ ti wọn pari ipade naa la tun gbọ pe wọn ṣepade ẹgbẹ oṣelu APC. Ile agbara tiluu Abuja lawọn ipade naa ti waye.
Diẹ re e lara awọn fọto bi eto ipade naa ṣe lọ.
No comments:
Post a Comment