Gbogbo awọn akẹkọọ patapata nipinlẹ Ondo ti wọn kopa nibi eto ayẹyẹ imọ-ẹrọ tọdun 2019 ni wọn ko le tete gbagbe ọjọ naa pẹluu oriṣiriṣi ẹkọ ti wọn ri kọ nibẹ.
Eto tọdun yi ti wọn pe akori ẹ ni "Our World of Science; Hope for
Industrialization in Ondo State" lo waye ninu gbagede Community Education Resource
Centre to wa ni Ayedun Quarters niluu Akurẹ.
Diẹ re lara awọn fọto bi eto naa ṣe lọ.
No comments:
Post a Comment