Bi idije England Premier League ti igba kọkanla ṣe ti pari lọjọ Aiku (Sande) ana, eyi i lawọn agbabọọlu to ba bọọlu sawọn julọ latigba ti idije naa ti bẹrẹ.
Ọmọ ẹgbẹ agbabọọlu Leicester City to n gba aarin si iwaju, Jamie
Vardy lo ṣi gba bọọlu sawọn julọ pẹlu goolu mẹwaa, eyi to fi n bori Sergio Aguero ti ẹgbẹ agbabọọlu Manchester City ati Tammy Abraham ti ẹgbẹ agbabọọlu Chelsea tawọn jọ n figagbaga pẹluu goolu mẹsan-mẹsan an.
Orukọ Ẹgbẹ Agbabọọlu Goolu
Jamie Vardy Leicester City Mẹwaa (10)
Sergio Aguero Manchester City Mẹsan an (9)
Tammy Abraham Chelsea Mesan an (9)
Pierre-Emerick
Aubameyang Arsenal Mẹjọ (8)
Raheem Sterling Manchester City Meje (7)
Sadio Mane Liverpool Mẹfa (6)
Teemu Pukki Norwich Mẹfa (6)
Harry Kane Tottenham Mẹfa (6)
Mohamed Salah Liverpool Marun un (5)
Marcus Rashford Manchester United Marun un (5)
Callum Wilson Bournemouth Marun un (5)
Christian Pulisic Chelsea Mẹrin (4)
Ashley Barnes Burnley Mẹrin (4)
Bernardo Silva Manchester City Mẹrin (4)
Jordan
Ayew Crystal Palace Mẹrin (4)
Neal Maupay Brighton Mẹrin (4)
Mason Mount Chelsea Mẹrin (4)
Chris
Wood Burnley Mẹrin (4)
No comments:
Post a Comment